Jẹ́nẹ́sísì 26:29 BMY

29 pé ìwọ kì yóò ṣe wá ní ibi, bí àwa pẹ̀lú kò ti ṣe ọ́ ní aburú, tí a sì ń ṣe ọ́ dáradára, tí a sì rán ọ jáde ní àlàáfíà láì ṣe ọ́ ní ibi, kíyèsi Olúwa sì ti bùkún fún ọ.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 26

Wo Jẹ́nẹ́sísì 26:29 ni o tọ