Jẹ́nẹ́sísì 26:31 BMY

31 Ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì wọn búra fún ara wọn. Ísáákì sì rán wọn lọ, wọ́n sì lọ ní àlàáfíà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 26

Wo Jẹ́nẹ́sísì 26:31 ni o tọ