Jẹ́nẹ́sísì 27:18 BMY

18 Jákọ́bù wọlé lọ sí ọ̀dọ̀ baba rẹ̀ ó sì wí pé, “Baba mi”,Baba rẹ sì dáhùn pé, “Èmi nìyí, ìwọ ta ni, ọmọ mi?”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 27

Wo Jẹ́nẹ́sísì 27:18 ni o tọ