Jẹ́nẹ́sísì 27:27 BMY

27 Ó sì súnmọ ọn, ó sì fẹnu kò ó ní ẹnu. Nígbà tí Ísáákì gbọ́ òórùn aṣọ rẹ̀, ó súre fún-un ó wí pé:“Wò ó òórùn ọmọ miDà bí òórùn okotí Olúwa ti bùkún.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 27

Wo Jẹ́nẹ́sísì 27:27 ni o tọ