Jẹ́nẹ́sísì 27:33 BMY

33 Nígbà náà ni Ísáákì wárìrì gidigidi, ó sì wí pé, “Ta ni ẹni náà, tí ó ti pa ẹran igbó tí ó sì ti gbe wá fún mi, tí mo sì ti jẹ ẹ́ kí ó tó dé? Mo sì ti súre fún un sì wò ó dájúdájú a ó sì bùkún un”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 27

Wo Jẹ́nẹ́sísì 27:33 ni o tọ