Jẹ́nẹ́sísì 27:36 BMY

36 Ísọ̀ sì wí pé, “Lásán ni a pe orúkọ rẹ̀ ní Jákọ́bù, (Arẹ́nijẹ) bí? Ní ìgbà méjì yìí ni ó ti tàn mí jẹ: ní àkọ́kọ́, ó gba ogún ìbí mi, nísinsinyìí, ó tún gba ìbùkún mi! Áà! Baba mi, ṣe o kò wá fi ìre kankan sílẹ̀ fun mi ni?”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 27

Wo Jẹ́nẹ́sísì 27:36 ni o tọ