Jẹ́nẹ́sísì 27:45 BMY

45 Nígbà tí ẹ̀gbọ́n rẹ kò bá bínú sí ọ mọ́, tí ó sì ti gbàgbé ohun tí ìwọ ṣe sí i, èmí ó ránṣẹ́ sí ọ láti padà wá, Èéṣe tí èmi ó fi pàdánù ẹ̀yin méjèèjì ní ọjọ́ kan náà?”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 27

Wo Jẹ́nẹ́sísì 27:45 ni o tọ