Jẹ́nẹ́sísì 28:2 BMY

2 Dípò bẹ́ẹ̀ lọ sí Padani-Árámù, sí ilé Bétúélì, baba ìyá rẹ, kí ìwọ kí ó sì fẹ́ aya fún ara rẹ nínú àwọn ọmọbìnrin Lábánì arákùnrin ìyá rẹ.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 28

Wo Jẹ́nẹ́sísì 28:2 ni o tọ