Jẹ́nẹ́sísì 28:20 BMY

20 Jákọ́bù sì jẹ́ ẹ̀jẹ́ níbẹ̀ pé, “Bí Ọlọ́run yóò bá wà pẹ̀lú mi, tí yóò sì pa mí mọ́ ní ìrìnàjò mi tí mo ń lọ, tí yóò sì fún mi ní oúnjẹ láti jẹ àti aṣọ láti wọ̀,

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 28

Wo Jẹ́nẹ́sísì 28:20 ni o tọ