Jẹ́nẹ́sísì 28:5 BMY

5 Bẹ́ẹ̀ ni Ísáákì sì rán Jákọ́bù lọ. Ó sì lọ sí Padani-Árámù, lọ́dọ̀ Lábánì ọmọ Bétúélì, ará Árámíà, tí í ṣe arákùnrin Rèbékà ìyá Jákọ́bù àti Ísọ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 28

Wo Jẹ́nẹ́sísì 28:5 ni o tọ