Jẹ́nẹ́sísì 29:21 BMY

21 Jákọ́bù sì wí fún Lábánì pé, “Mo ti parí àsìkò tí a jọ ṣe àdéhùn rẹ̀, nítorí náà fún mi ní aya mi, kí òun lè ṣe aya fún mi.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 29

Wo Jẹ́nẹ́sísì 29:21 ni o tọ