Jẹ́nẹ́sísì 29:3 BMY

3 Nígbà tí gbogbo agbo ẹran bá péjọ pọ̀ sí ibẹ̀ tán ni àwọn darandaran yóò tó yí òkúta náà kúrò, tí wọn yóò sì fún àwọn ẹran náà ní omi, tí wọ́n bá sì ti ṣe bẹ́ẹ̀ tán, wọn yóò tún yí òkúta náà padà sí ẹnu kànga náà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 29

Wo Jẹ́nẹ́sísì 29:3 ni o tọ