Jẹ́nẹ́sísì 29:32 BMY

32 Líà sì lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Rúbẹ́nì, nítorí ó wí pé, “Nítorí Ọlọ́run ti mọ ìpọ́njú mi, dájúdájú, ọkọ mi yóò fẹ́ràn mi báyìí.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 29

Wo Jẹ́nẹ́sísì 29:32 ni o tọ