Jẹ́nẹ́sísì 29:34 BMY

34 Ó sì tún lóyún, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì wí pé, “Nigbà yìí ni ọkọ mi yóò fara mọ́ mi, nítorí tí mo ti bí ọmọkùnrin mẹ́ta fún un,” nítorí náà ni ó ṣe pe orúkọ rẹ̀ ní Léfì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 29

Wo Jẹ́nẹ́sísì 29:34 ni o tọ