Jẹ́nẹ́sísì 3:1 BMY

1 Ejò ṣáà ṣe alárékérekè ju àwọn ẹranko igbó yóòkù tí Olúwa Ọlọ́run dá lọ. Ó sọ fún obìnrin náà pé, “Ǹjẹ́ òtítọ́ há ni Ọlọ́run wí pé, ‘Ẹ̀yin kò gbọdọ̀ jẹ èṣo èyíkéyìí lára àwọn igi tí ó wà nínú ọgbà’?”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 3

Wo Jẹ́nẹ́sísì 3:1 ni o tọ