Jẹ́nẹ́sísì 3:22 BMY

22 Olúwa Ọlọ́run sì wí pé, “Ọkùnrin náà ti dàbí ọ̀kan lára wa, ó mọ rere àti búburú. A kò gbọdọ̀ jẹ́ kí ó na ọwọ́ rẹ̀ kí ó mú lára èṣo igi ìyè kí ó sì jẹ, kí ó sì wà láàyè títí láéláé.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 3

Wo Jẹ́nẹ́sísì 3:22 ni o tọ