Jẹ́nẹ́sísì 30:1 BMY

1 Nígbà tí Rákélì rí i pe òun kò bímọ, ó bẹ̀rẹ̀ sí ṣe ìlara sí Líà, arabìnrin rẹ̀, ó sì wí fún Jákọ́bù pé, “Fún mi lọmọ, bí kò ṣe bẹ́ẹ̀, èmi ó kú”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 30

Wo Jẹ́nẹ́sísì 30:1 ni o tọ