Jẹ́nẹ́sísì 30:14 BMY

14 Ní ọjọ́ kan, ní àkókò ìkórè ọkà jéró, Rúbẹ́nì jáde lọ sí oko, ó sì rí ọ̀gbòn mádírákì, ó sì mu un tọ Líà ìyá rẹ̀ wá. Rákélì sì wí fún Líà pé, “Jọ̀wọ́ fún mi ní ara mádírákì tí ọmọ rẹ mú wá.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 30

Wo Jẹ́nẹ́sísì 30:14 ni o tọ