Jẹ́nẹ́sísì 30:24 BMY

24 Ó sì pe orúkọ rẹ̀ ni Jóṣẹ́fù, ó sì wí pé, “Ǹjẹ́ kí Olúwa kí ó fi ọmọkùnrin mìíràn kún-un fún mi.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 30

Wo Jẹ́nẹ́sísì 30:24 ni o tọ