Jẹ́nẹ́sísì 30:27 BMY

27 Ṣùgbọ́n Lábánì wí fún un pé, “Bí o bá ṣe pé mo rí ojúrere rẹ, jọ̀wọ́ dúró, nítorí, mo ti ṣe àyẹ̀wò rẹ, mo sì rí i pé Olúwa bùkún mi nítorí rẹ.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 30

Wo Jẹ́nẹ́sísì 30:27 ni o tọ