Jẹ́nẹ́sísì 30:43 BMY

43 Nítorí ìdí èyí, Jákọ́bù di ọlọ́rọ̀ gidigidi, agbo-ẹran rẹ̀ pọ̀ àti àwọn ìránṣẹ́-kùnrin, ìránṣẹ́-bìnrin pẹ̀lú ràkúnmí àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 30

Wo Jẹ́nẹ́sísì 30:43 ni o tọ