Jẹ́nẹ́sísì 30:6 BMY

6 Rákélì sì wí pé, “Ọlọ́run ti ṣe ìdájọ́ mi; ó sì ti gbọ́ ohún ẹ̀bẹ̀ mi, ó sì fún mi ni ọmọkùnrin kan.” Nítorí ìdí èyí ni ó ṣe pe orúkọ rẹ̀ ní Dánì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 30

Wo Jẹ́nẹ́sísì 30:6 ni o tọ