Jẹ́nẹ́sísì 31:28 BMY

28 Ìwọ kò tilẹ̀ jẹ́ kí èmi fi ẹnu ko àwọn ọmọ ọmọ mi lẹ́nu, pẹ̀lú àwọn ọmọbìnrin mi pé ó dìgbà? Ohun tí ìwọ ṣe yìí jẹ́ ìwà òmùgọ.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 31

Wo Jẹ́nẹ́sísì 31:28 ni o tọ