Jẹ́nẹ́sísì 31:32 BMY

32 “Ṣùgbọ́n bí o bá ri ẹnikẹ́ni pẹ̀lú ère rẹ, kí ẹni náà di òkú.” Ó tún wí pé, “Níwájú gbogbo ìbátan wa báyìí, wò ó fúnra rẹ, bí o bá rí ohunkóhun tí í ṣe tìrẹ, mú un.” Jákọ́bù kò sì mọ̀ pé, Rákélì ni ó jí àwọn òrìṣà náà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 31

Wo Jẹ́nẹ́sísì 31:32 ni o tọ