Jẹ́nẹ́sísì 31:36 BMY

36 Inú sì bí Jákọ́bù, ó sì pe Lábánì ní ìjà pé, “Kín ni ẹ̀ṣẹ̀ mi? Ẹ̀ṣẹ̀ wo ni mo ṣẹ̀ ọ tí ìwọ fi ń lépa mi bí ọ̀daràn?

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 31

Wo Jẹ́nẹ́sísì 31:36 ni o tọ