Jẹ́nẹ́sísì 31:5 BMY

5 Ó sì wí fún wọn pé, “Mo rí i wí pé ìwà baba yín sí mi ti yí padà sí ti tẹ́lẹ̀, ṣùgbọ́n Ọlọ́run baba mi wà pẹ̀lú mi.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 31

Wo Jẹ́nẹ́sísì 31:5 ni o tọ