Jẹ́nẹ́sísì 31:7 BMY

7 Ṣíbẹ̀ṣíbẹ̀ baba yín ti rẹ́ mi jẹ ní ẹ̀ẹ̀mẹ́wàá ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni ó sì ti yí owó iṣẹ́ mi padà. Ṣùgbọ́n Ọlọ́run kò jẹ́ kí ó le è pa mi lára.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 31

Wo Jẹ́nẹ́sísì 31:7 ni o tọ