Jẹ́nẹ́sísì 32:16 BMY

16 Ó sì fi wọ́n lé àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ́wọ́ ní ọ̀wọ̀ọ̀wọ́, ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ lọ ṣáájú mi, kí ẹ sì jẹ́ kí àlàfo wà láàrin ọ̀wọ́ agbo ẹran kọ̀ọ̀kan sí èkeji.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 32

Wo Jẹ́nẹ́sísì 32:16 ni o tọ