Jẹ́nẹ́sísì 32:18 BMY

18 Nígbà náà ni ìwọ yóò wí pé, ‘Ti ìránṣẹ́ rẹ Jákọ́bù ni wọ́n. Ẹ̀bùn ni ó sì fi wọ́n ṣe fún Ísọ̀ olúwa mi, òun pàápàá ń bọ̀ lẹ́yìn wa.’ ”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 32

Wo Jẹ́nẹ́sísì 32:18 ni o tọ