Jẹ́nẹ́sísì 32:25 BMY

25 Ṣùgbọ́n nígbà tí ọkùnrin náà rí i pé òun kò le borí Jákọ́bù, ó fọwọ́ kan-án ní ọ̀ọ́kán ibi tí eegun itan ti bẹ̀rẹ̀, egungun náà sì yẹ̀ kúrò lórí ìké, bí ó ti ń ja ìjàkadì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 32

Wo Jẹ́nẹ́sísì 32:25 ni o tọ