Jẹ́nẹ́sísì 32:30 BMY

30 Jákọ́bù sì pe orúkọ ibẹ̀ ní Pẹ́núẹ́lì pé, “Mo rí Ọlọ́run ní ojúkojú, ṣíbẹ̀ a dá ẹ̀mí mi sí.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 32

Wo Jẹ́nẹ́sísì 32:30 ni o tọ