Jẹ́nẹ́sísì 33:15 BMY

15 Ísọ̀ wí pé, “Jẹ́ kí n fi díẹ̀ sílẹ̀ fún ọ nínú àwọn ọkùnrin mi nígbà náà.”Jákọ́bù wí pé, “Èéṣe, àní kí n sáà rí ojú rere olúwa mi?”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 33

Wo Jẹ́nẹ́sísì 33:15 ni o tọ