Jẹ́nẹ́sísì 33:5 BMY

5 Nígbà tí Ísọ̀ sì ṣe àkíyèsí àwọn ìyàwó àti ọmọ Jákọ́bù, ó bèèrè lọ́wọ́ Jákọ́bù pé, “Ti tani àwọn wọ̀nyí?”Jákọ́bù sì fèsì wí pé, “Èyí ni àwọn ọmọ tí Ọlọ́run nínú àánú rẹ̀ ti fi fún ìránṣẹ́ rẹ.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 33

Wo Jẹ́nẹ́sísì 33:5 ni o tọ