Jẹ́nẹ́sísì 34:12 BMY

12 Iyekíye tí owó orí rẹ̀ bá jẹ́ àti ẹ̀bùn gbogbo tí ẹ bá fẹ́, bí ó ti wù kí ó pọ̀ tó, èmi yóò san-án, kí ẹ sáà jẹ́ kí ń fi ọmọ náà ṣe aya.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 34

Wo Jẹ́nẹ́sísì 34:12 ni o tọ