Jẹ́nẹ́sísì 34:14 BMY

14 Wọ́n wí fún wọn pé, “Àwa kò le ṣe nǹkan yìí láti fi arábìnrin wa fún aláìkọlà, nítorí àbùkù ni èyí yóò jẹ́ fún wa.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 34

Wo Jẹ́nẹ́sísì 34:14 ni o tọ