Jẹ́nẹ́sísì 34:25 BMY

25 Lẹ́yìn ọjọ́ kẹ́ta, nígbà tí gbogbo wọn sì wà nínú ìrora. Àwọn ọmọ Jákọ́bù méjì, Símónì àti Léfì tí ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n fún Dínà, sì mú idà wọn pẹ̀lú ìgboyà, wọ́n sì pa gbogbo ọkùnrin ìlú náà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 34

Wo Jẹ́nẹ́sísì 34:25 ni o tọ