Jẹ́nẹ́sísì 34:3 BMY

3 Ọkàn rẹ sì fà sí Dínà ọmọ Jákọ́bù gan-an, ó sì fẹ́ràn rẹ̀ ó sì bá ọmọbìnrin náà sọ̀rọ̀-ìfẹ́.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 34

Wo Jẹ́nẹ́sísì 34:3 ni o tọ