Jẹ́nẹ́sísì 34:30 BMY

30 Nígbà náà ni Jákọ́bù wí fún Símónì àti Léfì wí pé, “Ẹ̀yin ti kó ìyọnu bá mi nípa sísọ mí di olóòórùn láàrin ará Kénánì àti Pérésì, tí ó ń gbé ilẹ̀ yìí. Àwa kò pọ̀, bí wọn bá wá parapọ̀ sígun sí wa, gbogbo wa pátapáta ni wọn yóò parun.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 34

Wo Jẹ́nẹ́sísì 34:30 ni o tọ