Jẹ́nẹ́sísì 35:14 BMY

14 Jákọ́bù sì fi òkúta ṣe òpó kan sí ibi tí Ọlọ́run ti bá a sọ̀rọ̀ ó sì ta ọrẹ ohun mímu (wáìnì) ní orí rẹ̀, ó sì da òróró ólífì sí orí rẹ̀ pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 35

Wo Jẹ́nẹ́sísì 35:14 ni o tọ