Jẹ́nẹ́sísì 36:12 BMY

12 Élífásì ọmọ Ísọ̀ sì tún ní àlè tí a ń pè ní Tímúnà pẹ̀lú, òun ló bí Ámálékì fún un. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ-ọmọ Ádà aya Ísọ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 36

Wo Jẹ́nẹ́sísì 36:12 ni o tọ