Jẹ́nẹ́sísì 36:18 BMY

18 Àwọn ọmọ Óhólíbámà aya Ísọ̀:Jéúsì, Jálámì, àti Kórà, àwọn wọ̀nyí ló jẹ́ olorí ìdílé tí ó ti ọ̀dọ̀ Óhólíbámà ọmọ Ánà, ìyàwó Ísọ̀ wá.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 36

Wo Jẹ́nẹ́sísì 36:18 ni o tọ