Jẹ́nẹ́sísì 36:24 BMY

24 Àwọn ọmọ Ṣíbéónì:Áíyà àti Ánà. Èyí ni Ánà tí ó rí ìṣun omi gbígbóná ní inú asálẹ̀ bí ó ti ń da àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ Ṣébéónì baba rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 36

Wo Jẹ́nẹ́sísì 36:24 ni o tọ