Jẹ́nẹ́sísì 36:40 BMY

40 Àwọn wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ìjòyè tí ó ti ọ̀dọ̀ Ísọ̀ jáde wá, ní orúkọ ìdílé wọn, bí ìpínlẹ̀ wọn ti rí:Tínínà, Álífánì, Jététì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 36

Wo Jẹ́nẹ́sísì 36:40 ni o tọ