Jẹ́nẹ́sísì 36:7 BMY

7 Ohun ìní wọn pọ̀ ju èyí tí àwọn méjèèjì lè máa gbé ní ojúkan lọ. Ilẹ̀ tí wọ́n wà kò le gba àwon méjèèjì nítorí àwọn ohun ọ̀sìn wọn.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 36

Wo Jẹ́nẹ́sísì 36:7 ni o tọ