Jẹ́nẹ́sísì 37:17 BMY

17 Ọkùnrin náà dáhùn pé, “Wọ́n ti kúrò ní ìhín, mo gbọ́ tí wọ́n ń wí pé, ‘Ẹ jẹ́ kí a lọ sí Dótanì.’ ”Jósẹ́fù sì wá àwọn arákùnrin rẹ̀ lọ, ó sì rí wọn ní tòsí Dótanì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 37

Wo Jẹ́nẹ́sísì 37:17 ni o tọ