Jẹ́nẹ́sísì 37:24 BMY

24 wọ́n mú un, wọ́n sì jù ú sínú kòtò. Kòtò náà sì ṣófo, kò sí omi nínú un rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 37

Wo Jẹ́nẹ́sísì 37:24 ni o tọ