Jẹ́nẹ́sísì 37:34 BMY

34 Nígbà náà ni Jákọ́bù fa aṣọ rẹ̀ ya, ó sì wọ aṣọ ọ̀fọ̀, ó sì sọ̀fọ̀ ọmọ rẹ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjọ́

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 37

Wo Jẹ́nẹ́sísì 37:34 ni o tọ