Jẹ́nẹ́sísì 37:4 BMY

4 Nígbà tí àwọn arákùnrin rẹ̀ rí i pé baba àwọn fẹ́ràn rẹ̀ ju gbogbo wọn lọ, wọ́n kóríra rẹ̀, wọ́n sì ń fi ẹ̀tanú bá a gbé, kò sì sí àlàáfíà láàrin wọn.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 37

Wo Jẹ́nẹ́sísì 37:4 ni o tọ