Jẹ́nẹ́sísì 37:8 BMY

8 Àwọn arákùnrin rẹ̀ wí fún un pé, “Ìwọ ń gbérò àti jọba lé wa lórí bí? Tàbí ìwọ ó ṣe olórí wa ní tòótọ́?” Wọn sì túbọ̀ kórìíra rẹ̀ sí i, nítorí àlá rẹ̀ àti nítorí ohun tí ó wí.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 37

Wo Jẹ́nẹ́sísì 37:8 ni o tọ