Jẹ́nẹ́sísì 38:11 BMY

11 Nígbà náà ni Júdà wí fún Támárì, ìyàwó ọmọ rẹ̀ pé, “Lọ máa gbé bí opó ní ilé baba rẹ, títí tí Ṣélà yóò fi dàgbà ó lérò pé òun náà lè kú bí àwọn arákùnrin rẹ̀ tó kù.” Nígbà náà ni Támárì ń lọ gbé ilé baba rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 38

Wo Jẹ́nẹ́sísì 38:11 ni o tọ